Happy birthday to the indefatigable leader Omooba Segun Adewale (OSA).

Onikoyi Eso

Omo Onikoyi akoko

Omo agba tin yarun Ote

Omo ogun lere joja lo

Omo lakaba aonikoyi

Omo agbon ti o ri ku sa telegba ma di

Pelemo lojo ta r’ogun oba

Eso r’ogun o yo sese mote ore

Omi kan ti n be nikoyi ile, t’enikan o gbodo mu

Ero ona ko gbodo bu sanse

Eso Ikoyi de be lo bu boju

Omo koyan koyan laakoyan

Omo Agun ‘yon b’ogun

Isere Ikoyi omo adile kiku tode

Ikoyi kii j'okete, Ikoyi t’o ba j’okete

Ogun ni won o lo

Ikoyi kii gbo'fa lehin,

iwaju ni won ti ngba ota

Ikoyi t’o ba gbo'fa lehin

Ojo ara l’onse

Edumare Jowo Bawa Da Ilu Ikoyi Si

Amin, Ase.

Once again, happy birthday to you Leader. Bo'mosa oji'yo l'obe.